Loading video...
Video Failed to Load
Ẹ ba mi mu ọkan. Ẹ ṣeun pupọ!
19,797 views • 1 year ago •via X (Twitter)
35 Comments

We have sweet melon.. that should be "bara didun" Not all watermelon are sweet, so "bara olómi" will be fine.. just like the name '"Water + melon" = bara + olomi

B. Bara olomi

D. Baara Olomididun lo dara ju nitori wipe o se ak’opo Baara (melon) pelu omididun (sweet juice/water) ti o se akoja oruko re ni ede Oyinbo, iyen watermelon. E ku ise opolo, eyin oluko ati ojogbon ti e n ba wa se awon iwadi yii. Olodumare yoo tunbo maa ran yin lowo o🙏🏽

Bara- Melon Omi- Water I will go with Bara-olomi

@arojinle1 should know It's his best fruit

B. Bara olomi

Please, sir can you also consider Gold melon or have it been named already before proceeding to Watermelon... Thanks

Bara Oloyin nko? Gbogbo wa la m'ope didun ni oyin man dun

Bara- Melon Omi- Water Bara-olomi is wey better sir Bara olomi fara pe ede geesi re Bara olomi, Water melon Water melon, Bara olomi Bara olomi, water melon Water melon, Bara olomi

I go with B. Bara olomi.

B

B

B

Bara oyinbo olomididun

B

Bara olomi

There is also the yellow melon which is watery and sweet as well.

B

Bara olomi

Bárà ólòmídìdùn

Bara olomididun, that gives a complete description.

Bara Olomi lo fara pe ede geesi re. Bara Olomi...ni o dara ju lo ni iwoye mi

Bara Olomi

Bara didun

Ale pe ni (bara olomiadun) tabi (baraaladun)

@Sci_in_Yoruba mo fẹ́ pe àkíyèsí yín sí ìlo àmì ohùn. Ó ṣe pàtàkì. Ẹ seun púpò

B. Bara olomi

B

bara olomididun

Bára olómi dídùn

Bara Olomididun

Àsàyàn "B" ni mo mú

Bara olomididun

Bara olomi

Bàrà olómidúndùn
