正在加载视频...

视频加载失败

Ki ni UPDATE ni Yoruba?

10,916 次观看 • 1 年前 •via X (Twitter)

9 条评论

Science in Yoruba 的头像
Science in Yoruba1 年前

Your responses are helping me develop a book that will contain this new vocabulary and help develop the Yorúbà language further. Thanks for participating in this research!!!

Science in Yoruba 的头像
Science in Yoruba1 年前

Awọn ariwisi yin n ran mi lọwọ lati ṣe iwe ti yoo ni awọn ọrọ tuntun yi ti yoo si ṣe iranwọ lati mu ede Yoruba gbooro sii. Ẹ ṣeun ti ẹ n kopa ninu iṣẹ iwadi yi. Mo dupẹ pupọ

Comrd. QUADRI 𝓸.𝓵.𝓪 ♎💍☀ 的头像
Comrd. QUADRI 𝓸.𝓵.𝓪 ♎💍☀1 年前

If update is “so dotun” what is renew?

Bashir Kola Turawa 的头像
Bashir Kola Turawa1 年前

Olùkọ́, ṣé a lè pe update ní "ìmúdójúìwọ̀n"?

Olatunji of Naija #Obidient 🇳🇬🇳🇬🇳🇬 的头像
Olatunji of Naija #Obidient 🇳🇬🇳🇬🇳🇬1 年前

Update - bó se n lo

DAMILOLA OLUBORODE 的头像
DAMILOLA OLUBORODE1 年前

Update máa jẹ "Ìsọdọ̀tun", system update máa jẹ "Ìsọdọ̀tun ètò" amo kí wa ni "Upgrade" máa jẹ?

Bldr. Nathaniel Abiodun Emmanuel 的头像
Bldr. Nathaniel Abiodun Emmanuel1 年前

Isodotun seems like renewal to me. Nonetheless ise nla len se olootu.

Science in Yoruba 的头像
Science in Yoruba1 年前

Ǹjẹ́ ẹ mọ pe update (v) àti renew lè jẹ ààrọ̀ (synonyms)? Ẹ ṣeun lọpọlọpọ

Science in Yoruba 的头像
Science in Yoruba1 年前

Atunto = restructuring. Ẹ ṣeun lọpọlọpọ

相关视频