Video wird geladen...

Video konnte nicht geladen werden

Zur Startseite

. , : ; " " ! ? ní Yoruba

13,689 Aufrufe • vor 1 Jahr •via X (Twitter)

11 Kommentare

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Thanks for your contribution. Please note that I am considering the names of these symbols beyond just writing an essay. I am also considering their efficiency in computational environments and mathematical notations. Thanks for supporting this research.

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa (Ẹ ṣeun fun idasi yin. Ẹ dakun, ẹ kiesi pe  agbeyẹwo mi lori orukọ awọn ami yi kọja kikọ arokọ nikan. Mo n ṣe agbeyẹwo ṣiṣe deede wọn naa fun awọn ibi ifẹrọṣesiro (computational environments)  ati  ifamisọrọ oniṣiro (mathematical notations).

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Ẹ ṣeun bi ẹ ṣe n ran iṣẹ iwadi yi lọwọ.

Profilbild von Tiwantiwa Hub
Tiwantiwa Hubvor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Gbogbo rẹ̀ ló ṣe rẹ́gí. Ẹ kú ìṣe takuntakun, baba

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Mo dupẹ pupọ, ọ̀jọ̀gbọ́n!

Profilbild von 𝕊𝔸𝕐_𝕊𝕡𝕠𝕣𝕥𝕤𝕄𝕖𝕕𝕚𝕒
𝕊𝔸𝕐_𝕊𝕡𝕠𝕣𝕥𝕤𝕄𝕖𝕕𝕚𝕒vor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Imoran mi leyi: Fullstop = (Àmì) Idanuduro Comma = Isemi or idanuduro ranpẹ Single Apostrophe = Tiun Double Apostrophe = Tiun Tiun (Tiun meji) Colon = (Àmì) fun apẹẹrẹ (olodindin) Semicolon = fun apẹẹrẹ (àbò) Exclamation mark = (Àmì) ìjayà Question mark = (Àmì) ibeere

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Ẹ ṣeun fun idasi yin. Ẹ dakun, ẹ kiesi pe  agbeyẹwo mi lori orukọ awọn ami yi kọja kikọ arokọ nikan. Mo n ṣe agbeyẹwo ṣiṣe deede wọn naa fun awọn ibi ifẹrọṣesiro (computational environments)  ati  ifamisọrọ oniṣiro (mathematical notations).

Profilbild von Lakejobi
Lakejobivor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa History will be kind to you

Profilbild von D Vearse
D Vearsevor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa After approval and meeting old people for advise. Can you rewrite our dictionary

Profilbild von Ifedayo
Ifedayovor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Bracketi ati Quotation mark: ("") nko? E ku ise ati oro wa Sir.

Profilbild von Science in Yoruba
Science in Yorubavor 1 Jahr

@AKakanfo @arojinle1 @blockofbuilder @ThinkYoruba_1st @YorubaNationCH @EaYoruba @egbeatelewo @InsideOsogbo @Yorubaness @omoyorubaniwa Mo ń mú ẹyẹ bọ̀ lapo ni, baba. Ẹ ó rí ọwọ mi laipẹ. Ẹ ṣeun gan-an

Ähnliche Videos