Yoruba content only 😍Oya complete this ✅
@eludayo_170 B takipçi
27.442 görüntüleme
36 Yorum
Yorumlar X (Twitter) üzerindeki orijinal gönderiden alınmıştır

@princeifeoluw14
Faaji-----igbadun Gafara----- idariji Idoti-----eeri Sababi----idi Ijamba-----ijamba Wakati-----akoko Adura-----iwure Hope I got it😂😂😂🫢
69 beğeni

@eludayo_1
🙌🏽🙌🏽🙌🏽
8 beğeni

@princeifeoluw14
Different from the video 😂😂
1 beğeni

@Emmanuelitunu
Ẹ jẹ ká ro ìjìnlè dáadáa. Gaara nìkan ni èdè ayalo tó wà nínú àkọsílẹ̀ yí ọ. Gafara yí je'yo nínú èdè àwọn ará òkè oya àti ti àwọn ará ìlà ọrùn. Sababi yàtọ̀ tó kongẹ, wọn o bára mú ní lílọ àti ní ìtumò. Mo ṣe kongẹ owó ni ile ẹmu. Nko lè sọ pé mo ṣe sababi owo
8 beğeni

@Olaeleye01
Ijamba Ìpalára
7 beğeni

@eludayo_1
No

@KejiShoneye
Welldone... However, Sababi should be Okunfa and not Konge I think
4 beğeni

@MelvinJacs
Wakati... Aaya Adura... isure Idọti... Àtàn
3 beğeni

@taofeek_ab92034
Wakati-Akoko Adura-Iwure
3 beğeni

@IQsulaiman
Wakati - Àsìkò Adorable- ìwúre
2 beğeni

@Matseun
Wákàtí = Àkókò Àdúrà = Ìwúre
2 beğeni

@hayzed0709
Àsìkò Iwure
2 beğeni

@phantomXsly
I can’t even use the Ojulowo Ede, even the Iyawo Ede in some cases. Sadly, Yoruba is not the only language having this problem, every other languages are too.
2 beğeni

@ebenezerbablola
Ákókó Íwúré
1 beğeni

@Zeessentials
Wakati…… Asiko Adura ……. Iwure
1 beğeni

@Ellyment_247
@bayalsa27 Akoko Iwure
1 beğeni

@Tosign4
Wakati - Akiko Adura - Iwure
1 beğeni

@BiodunIshola2
Wakati..Akoko Adura…Iwure
1 beğeni

@AremuTaofeek10
Gáfárà - Yębá Wakati - Àkoko Àdurá - iwure
1 beğeni

@thundey27
That “Ijamba / Ęwu🙄














