正在加载视频...
视频加载失败
Ṣé ẹ wà ńbẹ́?
12 条评论

Sakalicious1 年前
Emi ati Sanko Rashidi je Omo akeeko ile orin Lodo Kehinde Oriyomi, ti o nko Orin Musulumi bayii. Ojo ti pe gan mi o lero pe Sanko ma si ranti mi mo, nitori majesin lawa ni gba na.

Arojinle1 年前
Ṣé oun tí ẹ̀ ń sọ ni pé Kẹ́hìndé Oríyọmí ti ń kọrin ní gbogbo ìgbà yẹn?

Solar Heavy1 年前
whoa have you heard this yet?

iam_orolabi1 年前
Mo wà níbè dáadáa, àmọ́ mo kéré jọjọ. Arákùnrin kan náà wá ti o n kọrin bíi tiẹ̀ nígbà náà. Mo ti gbàgbé orúkọ tiẹ̀.

Arojinle1 年前
Ṣáńkó, Kọ̀ǹténà, Kóńkóló, Múrí Ìkókó

Ọmọ Akin1 年前
sanko rasidi? omo 😊❤️

Sub-Pharmacist🍏1 年前
See steeze

Arojinle1 年前
Ó lágbára

oloore ridwan1 年前
Bẹ́ẹ̀ ni

Mayor1 年前
Omo Emi na ti di agba oooo ki eledumare ranmi lowo 😢🙏

D_Herb Master 💪🍀🍀🍀1 年前
Mo wa nibe o

Arojinle1 年前
Mo jẹ́rìí 🙌🏾
